Monday, March 26, 2018

Asayan Ewi Alohun Fun Itupale


Ewi alohun ni awon ewi abalaye awa Yoruba ti ogun logbon – on si ni ewi alohun. Die lara won ni

(1) Ese ifa: Eyi ni litireso ti oro mo Ifa ti a tun mo si orunmila. Awon olusin ifa ati awon babalawo lo maa ki ese ifa. Awon oro to maa n waye ninu ese ifa ni “Adie fun”, “kee pe tee jina” “Ebo riru” “Ijo ni n jo” “ayo ni n yo” lara awon ohun elo ifa dida ni ikin, opele, ibo, iroote, opon ifa, agere tabi awon ifa, apo ifa, ilu ifa.
Ori buruku kii wu tunle
A ki da ese asiwere mo lona
A kii mo ori oloye awujo
A dia fun moloowu
Tii se obinrin ogun
Ori ti yoo joba lola
Enikan ko mo on
Ki tiko taya yee peraa won
Wi were mo.

(2) Ijala: Eyi je mo ogun ati awon olusin re. iru ewi yii si maa n waye nibi ayeye bi isomoloruko, isile, odun ogun, igbeyawo, oye jije. Ikini, onti owe pipa, iwure lo maa n wa ninu ewi yii.

(3) Iwi tabi esa egungun: eyi je mo awon egungun. Yoruba gbagbo wi pe ara orun ni egungun bee ohun ti egungun ba wo bi aso no won pe ni eku. Egungun oni dan ni o n pesa, awon oje ati awon obinrin idile eleegun maa n kiwi tabi pesa. Lara ohun to maa n waye ninu ewi ewi yii ni iba, oriki, itan, orin, ijo ntori wipe awon egungun feran lati maa jo.
Oba kee pe mo juba kiba mi se
Iba ni n o ko ju na, are mi deyin
Mo juba baba mi………
Oje larinnaka, oko iyadunni
Omu leegun alare, a – bi – koko – leti aso.

(4) Ekun iyawo: Eji je mo igbeyawo. Aarin awon oyo ni ekun iyawo ti wopo. Nitori ifoya ti o maa n waye fun obinrin ti yoo fi ile obi re sile lo maa n mu ekun iyawo wa. ti igbeyawo ba ti ku ola ni omobinrin yoo maa sun ekun iyawo. Ekun iyawo maa n kun fun ibeere imoran, oriki orile, oro iwuri, iwure, awada, eyi si maa n la be lo.

Ere Idaraya


Ere idaraya le je ti gbangba tabi ti abe – ile. Ona meji ni a le pin ere idaraya si:
(1) Ere osupa                             (2) Ere ojumoomo
Ere osupa ni ere idaraya laarin awon ewe ti o maa n saba waye nigba ti ile ba ti su, sugbon ti osupa mole. Lara awon ere osupa ni Ekunmeran, Bojuboju, Ta lo ga ju laba;gbogbo awon ere wonyi je ti gbangba. Awon ere osupa ti o je ti abele ni a ti ri alo apamo ati alo apagbe.
Ere ojumoomo ni awon ere idaraya ti o maa n waye nigba ti ile koi su. Awon ere bi Ekunmeran, Bojuboju, Ta lo ga ju laba, ijakadi; awon wonyi je mo ita gbangba nigba awon ere bi ayo tita, okoto tita, ogo tita, awon ere wonyi je mo abe ile.
Awon ere ita gbangba maa n fun eniyan lokun ati agbara nigba ti awon ere abe ile maa n fun eniyan ni ironujinle ati iriri to gbooro sii.

Esin Ode Oni


Orisirisi esin loti wo awujo awa Yoruba; eyi tio yato si esin abalaye.
1.     Esin Musulumi eyi ti awon larubawa mu wo ile yi ni pa owo ati ogun jihaadi. Kurani ni iwe mimo ti won maa nka nigbati ile keu je ibi awon omode won ti maa bere eto Kurani mosalasi si ni awon Musulumi ti maa n jo sin.
Lara odun ti won maa n se ni (1) odun Ileya (odun ti a fi agbo dipo Summaila fun Buraimo) (2) odun itunu awe (odun ti won yoo gba awe ogbon ojo ninu osu Ramadani) (3) Odun Ijira (odun to je ibeere onka odun Musulumi) (4) ojo ibi anabi
2.     Esin Kirisiteni eyi ti awon oyibo mu mo ile Yoruba nipa owo sise ati ijinrere. Soosi ni won ti maa n josin. Bibeli si ni won maa nlo. Lara odun ti won maa n se ni (1) Keresimesi (odun to jemo ojo ibi jesu Kristi eyi to maa waye ninu osu ope) (2) Odun Ajinde (eyi ti o fi rapada ti Jesu fun gbogbo eda eniyan han)
3.     Esin Gurumaraji eyi ti o gbagbo wipe ohun ni Mesaya ti gbogbo aye n reti. Pupa ni awon olusin yii maa feran lato wo, won si feran odo pupa.
4.     Esin Ekanka; awon yii ni okan won maa n rin irinajo. Won gbagbo pe ile ile aye je ile eko nitori naa ninu irin ajo won ni won yoo ti maa keko laye.


Asa Ati Litireso Alohun


Asa ni se pelu iwa ati isesi awon eniyan agbegbe kan. Bi asa Yoruba se po to, bee naa ni litireso se n wa pelu re. litireso alohun ni a le pe ni litireso abalaye ntori wi pe ko wa ni kiko sile, inu opolo ni awon babanla wa ko o pamo sii, eyi si je ohun ajohunba fun gbogbo omo Yoruba. A le pin litireso alohun si: ewi, aroso oloro geere ati ere onitan.

Asa to suyo ninu litireso alohun po labe ewi ti o je litireso alohun lati ri ijala (a ri asa esin ogun, orin kiko, oriki, ise ode sise, isipa ose, etutu sise). “Ogun lakaaye osinmale /Ogun onire ooko mi/ Edan Ajoluwonran/Ogun ni n o sin n o sinba/ Ogun ni n o sin n o sinyan/ Ogun ni n o dimu/ Anjannu inu igbe/ Paramole abijawara”
Labe ere onitan ti o je mo litireso alohun lati ri ere eegun alare ( a ri asa orin toto, oriki, ifinisefe, okiti tita, idan pipa)

Labe aroso oloro geere ti o je mo lirireso alohun lati ri alo (a ri asa orin kiko, ebo riru, ofo pipa, isinku)

Sunday, March 25, 2018

Foniimu Faweli Ede Yoruba


Foniimu lo fi iyato han laarin itumo oro ka si ekeji ati iyato han laarin iro ede kan si ekeji. “/  /” ni akanmo ti a fi n se adato folium.
]
Bi a ba mo iyato laarin iro ede meji, a o mo iyato itumo laarin oro meji (iro “d” yato si iro “k”) eyi lo je ki a mo iyato laarin “da” ati “ka”.
A le pin fonimu faweli ede Yoruba si aranmupe ati airanmupe.


Orisirisi Oro-Ise


Oro – ise ni oro ti o n toka si ohun ti oluwa se ninu gbolohun. Oro ise naa ni a maa n pe ni koko gbolohun tabi Opomulero. Oro ise ni a fa ila si labe:-
i.                    Mojisola jeeba
ii.                  Ode paeranko
Orisirisi ilana ni a le gunle pin oro – ise, sugbon a o lo ilana silebu lati pin oro – ise.
(i)    Oro – ise oni silebu kan.
(ii)  Oro – ise oni silebu meji.
(a)  Oro – ise oni silebu kan kii ni ju eyo silebu kan lo, silebu yii si maa n je akanpo konsonanti ati faweli. Ko, je, gbin, wa, se, gbe, sun, fo, ji, gba.
(b) Oro – ise oni silebu meji kii ju eyo silebu meji lo; silebu yii si maa je akanpo konsonanti ati faweli. :- baje, gbagbo, pade, koja, jewo, pade. A tun le pin oro – ise onisilebu meji (a) Alela (b) Alaila
Oro – ise oni silebu meji elela le fi oro miran bo aarin oro ise ninu gbolohun
üBaje = Olu ba aga Ojo je
üGbagbo = mo gba olorun gbo
üTuka = Olori tu igbimo ka
üBawi = Tisa ba akeko wi.
Oro – ise onisilebu meji alaila je eyi ti ako le fi oro la oro – ise laarin ninu gbolohun.
Ø Pade = Ajayi pade Akin ni oja
Ø Pada = O pada si Eko
Ø Jewo = Olu jewo iro pipa
Ø Subu = Wale subu
A ti ya tabili fun orisirisi oro-ise pelu apeere, <<e lo ye e wo tabili naa wo>>

Eyan Oro Ninu Gbolohun


EYAN ORO NINU GBOLOHUN
Eyan oro ni oro ti a maa n lo lati fi yan gbolohun tabi ti a maa n lo lati fi fun gbolohun ni itumo ti o hunna ti too si yee olugbo daadaa. Lopolopo igba, a le pe eyan ni oro apejuwe.
Oro – oruko tabi aropo – oruko ti o ba n sise eyan ninu gbolohun ni a maa n pe ni eyan oro oruko.
Awon oro ti a fala si labe ni eyan ninu awon gbolohun wonyi:-
1.     Maalu Fulanisalo
2.     Ounje Adetobi
3.     Awa Okunringbon ju Obinrin lo
4.     Eyin Omodeferan ere sise
5.     Iya milowo
6.     Iwe re ti ya
7.     Ore re ni Dada
8.     Ise yin we omo mi
9.     Ile itaja yiitobi
10.            Ewu naadara pupo
EYAN ORO NINU GBOLOHUN
Eyan oro ni oro ti a maa n lo lati fi yan gbolohun tabi ti a maa n lo lati fi fun gbolohun ni itumo ti o hunna ti too si yee olugbo daadaa. Lopolopo igba, a le pe eyan ni oro apejuwe.
Oro – oruko tabi aropo – oruko ti o ba n sise eyan ninu gbolohun ni a maa n pe ni eyan oro oruko.
Awon oro ti a fala si labe ni eyan ninu awon gbolohun wonyi:-
1.     Maalu Fulanisalo
2.     Ounje Adetobi
3.     Awa Okunringbon ju Obinrin lo
4.     Eyin Omodeferan ere sise
5.     Iya milowo
6.     Iwe re ti ya
7.     Ore re ni Dada
8.     Ise yin we omo mi
9.     Ile itaja yiitobi
10.            Ewu naadara pupo

Saturday, March 24, 2018

ORE MI LATI OWO ADERIBIGBE MOROHUNMUBO M.


ORE MI LATI OWO ADERIBIGBE MOROHUNMUBO M.
Iwe itan “Ore Mi” je ere onise ti Aderibigbe Morohunmubo se akosile re. Ere onise yii da lori ife ati ore nini.
Ahunpo itan naa fi han pe ore meji kan wa (Sola ati Kunbi); won n ba ore won bon ni ogba yunifasiti. Sola je obinrin to rewa, omoluabi ati ore rere si Kunbi sugbon Kunbi je obinrin to rewa, alailekoo, oniwokuwo, olojukokoro, ati ore buruku si Sola.
Omo atapatadide ni Sola, awon obi re maa n sasokesasodo ki won to le ri owo jeun ati owo ile-iwe Sola. Ni idakeji ewe, omo onile-olona ni Kunbi, inu owo ni won bii si.
Bi o tile je pe inu owo ni a bi Kunbi si, ko si ohun ti o maa n te e lorun nitori akebaje omo nii se. Iwa ojukokoro re lo mu ki o fi oogun gba oko Sola, ore re. Yoruba bo, won ni, bi iro ba lo fun ogun odun, ojo kan bayii ni otito yoo ba a. laipe ojo, oogun sunko, ewe si baje; oju Femi ‘oko Sola’ la kedere, o si han sii kedere pe oun ti fi aimokan fi Sola, ololufe re, sile lati maa fe Kunbi.
Ika pa onika nitori pe Kunbi ko esan iwa odale re, se ni o ya weere.


Fonoloji Ede Yoruba


Fonoloji ni eto amulo iro ede kookan. Eyi tumo si ona ti a n gba lo iro ede. Fonoloji ni ona ti a n gba sin awon iro po, ni ona to je pe yoo fi fun wa ni itumo. Awon iro wonyi naa ni a maa n lo awon ami leta ropo.
Ninu imo eda – ede (Linguisiiki) awon onimo ede agbaye ni iulana ti won maa n gba ko awon iro alifabeeti ki o le baa ri bakaan naa kaariaye. Bi a se n ko iro faweli ati konsonanti pelu ilana akoto ede Yoruba yato si bi a se n ko pelu ilana fonetiiki.
Ilana akoto
a
e
e
i
o
o
u
an
in
on
un
en
Ilana Fonetiiki
a
e
e
i
o
o
u
a
i
o
u
e
Awon iro faweli ede Yoruba
Ilana Akoto
b
d
f
g
gb
h
j
k
l
m
n
p
r
s
s
t
w
y
Ilana Fonetiiki
b
d
f
g
gb
h
d
k
l
m
n
kp
r
s
s
t
w
y
Awon iro konsonanti ede Yoruba.
Fonoloji ni eto amulo iro ede kookan. Eyi tumo si ona ti a n gba lo iro ede. Fonoloji ni ona ti a n gba sin awon iro po, ni ona to je pe yoo fi fun wa ni itumo. Awon iro wonyi naa ni a maa n lo awon ami leta ropo.
Ninu imo eda – ede (Linguisiiki) awon onimo ede agbaye ni iulana ti won maa n gba ko awon iro alifabeeti ki o le baa ri bakaan naa kaariaye. Bi a se n ko iro faweli ati konsonanti pelu ilana akoto ede Yoruba yato si bi a se n ko pelu ilana fonetiiki.
Ilana akoto
a
e
e
i
o
o
u
an
in
on
un
en
Ilana Fonetiiki
a
e
e
i
o
o
u
a
i
o
u
e
Awon iro faweli ede Yoruba
Ilana Akoto
b
d
f
g
gb
h
j
k
l
m
n
p
r
s
s
t
w
y
Ilana Fonetiiki
b
d
f
g
/gb/
[gb]
/h/
[h]
/dj/
[dj]
/k/
[k]
/l/
[l]
/m/
[m]
/n/
[n]
/kp/
[kp]
/r/
[r]
/s/
[s]
/s/
[s]
/t/
[t]
/w/
[w]
/j/
[j]
Awon iro konsonanti ede Yoruba.

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday