Sunday, March 25, 2018

Orisirisi Oro-Ise


Oro – ise ni oro ti o n toka si ohun ti oluwa se ninu gbolohun. Oro ise naa ni a maa n pe ni koko gbolohun tabi Opomulero. Oro ise ni a fa ila si labe:-
i.                    Mojisola jeeba
ii.                  Ode paeranko
Orisirisi ilana ni a le gunle pin oro – ise, sugbon a o lo ilana silebu lati pin oro – ise.
(i)    Oro – ise oni silebu kan.
(ii)  Oro – ise oni silebu meji.
(a)  Oro – ise oni silebu kan kii ni ju eyo silebu kan lo, silebu yii si maa n je akanpo konsonanti ati faweli. Ko, je, gbin, wa, se, gbe, sun, fo, ji, gba.
(b) Oro – ise oni silebu meji kii ju eyo silebu meji lo; silebu yii si maa je akanpo konsonanti ati faweli. :- baje, gbagbo, pade, koja, jewo, pade. A tun le pin oro – ise onisilebu meji (a) Alela (b) Alaila
Oro – ise oni silebu meji elela le fi oro miran bo aarin oro ise ninu gbolohun
üBaje = Olu ba aga Ojo je
üGbagbo = mo gba olorun gbo
üTuka = Olori tu igbimo ka
üBawi = Tisa ba akeko wi.
Oro – ise onisilebu meji alaila je eyi ti ako le fi oro la oro – ise laarin ninu gbolohun.
Ø Pade = Ajayi pade Akin ni oja
Ø Pada = O pada si Eko
Ø Jewo = Olu jewo iro pipa
Ø Subu = Wale subu
A ti ya tabili fun orisirisi oro-ise pelu apeere, <<e lo ye e wo tabili naa wo>>

1 comment:

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday