Foniimu lo fi iyato han laarin itumo oro ka si ekeji ati iyato han laarin iro ede kan si ekeji. “/ /” ni akanmo ti a fi n se adato folium.
]
Bi a ba mo iyato laarin iro ede meji, a o mo iyato itumo laarin oro meji (iro “d” yato si iro “k”) eyi lo je ki a mo iyato laarin “da” ati “ka”.
A le pin fonimu faweli ede Yoruba si aranmupe ati airanmupe.
No comments:
Post a Comment