Awon oro ti o le toka si eyan, eranko, ilu, ohun elemi, ohun ailemi, ohun afoyemo ni a maa n pe ni oro – oruko. Apeere: omi, eweko, ole, ategun, abbl.
A le pin gbogbo oro-oruko Yoruba si meji:
(1) Oro oruko ti a seda
(2) Oro oruko ti a ko seda
Oro-oruko ti a ko seda: eyi ni a maa n pe oro – oruko ponnbele.
i. Oro – oruko ti a ko seda da itumo tire
ii. A kii fo oro – oruko ti a ko seda si wewe
iii. Itunmo oro naa yoo sonu ti a ba fo oro-oruko ti a ko seda si wewe
Oro oruko tia seda ni oro meji tabi meta ti a so di oro kan soso ti yoo si duro fun oro- oruko ninu gbolohun. Orisi ona ni a maa n gba seda oro – oruko.
1. Lilo afomo ibere
1. Lilo afomo aarin
2. Lilo apetunpe
3. Sise akanpe oro
(1) Ti a ko seda (2) Ti a seda
a) Afomo – ibere (afomo + oro-ise, afomo + oro ise + oroise, afomo + oro + oro oruko, afomo + apola ise, oni + oro oruko)
b) Afomo – aarin (omo + ki + omo, osu + mo + osu, igba + de + igba)
d) Apetunpe (pana + pana = panapana)
e) Akanpo oro (eran + oko = eranko)
No comments:
Post a Comment