Sunday, March 4, 2018

Isunki ati Aranmo

Isunki: eyi ni pipa ohun je ninu oro tabi apalo. A ni isunki ti a pa iro faweli je. Apeere
1.     Ikoko – koko
2.     Ibusun - busun  
3.     Iyanrin – yanrin
Ninu apalo, a le se iparoje faweli apeere:
1.     Bu obe = bube
2.     Je ijo   = jeyo
3.     Ewe oko= eweko
Aparo je konsonanti ni:
1.     Ekuro = ekuo
2.     Jowo = joo
3.     Otito = ooto
4.     Olorun = oloun
5.     Yoo=oo

Aranmo: ni ki faweli kan ran mo faweli keji. Ninu apalo ni eyi ti maa n sele, iye faweli ati silebu to wa ninu oro mejeeji ti a papo gbodo je iye kan naa pelu eyi ti a seda nipa aranmo
Apeere:
1.     Ile ise = ileese
2.     Ara oko = Arooko
3.     Iya egbe = iyeegbe
4.     Omo erin = omeerin.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday