Asa ni se pelu iwa ati isesi awon eniyan agbegbe kan. Bi asa Yoruba se po to, bee naa ni litireso se n wa pelu re. litireso alohun ni a le pe ni litireso abalaye ntori wi pe ko wa ni kiko sile, inu opolo ni awon babanla wa ko o pamo sii, eyi si je ohun ajohunba fun gbogbo omo Yoruba. A le pin litireso alohun si: ewi, aroso oloro geere ati ere onitan.
Asa to suyo ninu litireso alohun po labe ewi ti o je litireso alohun lati ri ijala (a ri asa esin ogun, orin kiko, oriki, ise ode sise, isipa ose, etutu sise). “Ogun lakaaye osinmale /Ogun onire ooko mi/ Edan Ajoluwonran/Ogun ni n o sin n o sinba/ Ogun ni n o sin n o sinyan/ Ogun ni n o dimu/ Anjannu inu igbe/ Paramole abijawara”
Labe ere onitan ti o je mo litireso alohun lati ri ere eegun alare ( a ri asa orin toto, oriki, ifinisefe, okiti tita, idan pipa)
Labe aroso oloro geere ti o je mo lirireso alohun lati ri alo (a ri asa orin kiko, ebo riru, ofo pipa, isinku)
No comments:
Post a Comment