EYAN ORO NINU GBOLOHUN
Eyan oro ni oro ti a maa n lo lati fi yan gbolohun tabi ti a maa n lo lati fi fun gbolohun ni itumo ti o hunna ti too si yee olugbo daadaa. Lopolopo igba, a le pe eyan ni oro apejuwe.
Oro – oruko tabi aropo – oruko ti o ba n sise eyan ninu gbolohun ni a maa n pe ni eyan oro oruko.
Awon oro ti a fala si labe ni eyan ninu awon gbolohun wonyi:-
1. Maalu Fulanisalo
2. Ounje Adetobi
3. Awa Okunringbon ju Obinrin lo
4. Eyin Omodeferan ere sise
5. Iya milowo
6. Iwe re ti ya
7. Ore re ni Dada
8. Ise yin we omo mi
9. Ile itaja yiitobi
10. Ewu naadara pupo

No comments:
Post a Comment