Thursday, November 29, 2018

Orisirisi Oro-Ise 2


ORISI ORO-ISE
APERRE WON
1.  oro-ise akanmoruko/aigbabo
Peran: Won peran
2. oro-ise aigbabo
Ji: Tola ji isu/ Tola ji i
3. oro-ise elela
Baje: Akekoo ba aga je
4. oro-ise ailela
Gbagbe: Gbogbo won gbagbe ise
5. oro-ise asinpo
Bu + Mu: Baba bu omi mu
6. oro-ise apepada
Mo: Aye ti mo mi mo Eledumare
7. oro-ise asokunfa
So: Ailowolowo so oko di iyawo



Ankoo Faweli

Eyi naa ni a tun mo si ijeyopo faweli ninu eko ede Yoruba. Ninu awon oro onisilebu meji ni a ti maa n se agbeyewo ankoo faweli. Idi re ni pe kii se gbogbo faweli lo le ba konsonanti kowo rin ninu oro onisilebu meji.

Ami "+" ni a fi toka ibasepo ninu tabili isale yii; nigba ti a fi ami "-" toka ainibasepo.

Bi faweli akoko ba je
Awon faweli ti o le tabi ti ko le ba ba a kegbe
a
e
ҿ
i
o
u
an
ẹn
in
ọn
un
a
+
+
+
+
+
+
+
+
-
+
+
+
e
-
+
-
+
+
-
+
-
-
+
-
-
ҿ
+
-
+
+
-
+
+
+
-
+
+
+
i
+
+
+
+
+
+
+
+
+
+
+
+
o
-
+
-
+
+
-
+
-
-
+
-
+
+
-
+
+
-
+
-
+
-
+
+
+
u
-
-
-
-
-
-
-
-
-
-
-
-



Saturday, November 17, 2018

Aro Dida (Yoruba Dye Making)


Awon ohun elo fun aro dida niyi: Omi-aluba, eeru soso-eyin, opolopo omi, ikoko arimole, ikoko kekeeke meji, opa-aro, aso funfun, elu, opon ti o fe ti eniyan le te aso le.

Ise obinrin ni ise yii bee si ni "aredu" je ikini fun awon alaro. Ise alaro ni ki o fi aro bu ewa kun aso nipa rire e sinu aro. Die lara awon ilu ti aro dida ti wopo ni Ibadan, Oyo, Osogbo, Iseyin, Iwo, Ijebu, ati Abeokuta.

Bi aro ko ba mu aso mo, iru aro bee ti sa niyen. Eyi ni won n pe ni okusu aro. Nigba yii, elu (coloring) ti won n lo ko ni wulo mo, won yoo da a nu; eyi ni won n pe ni sakiti.

Okusu aro (aro to ti sa) tun maa n wulo fun kikun ese-ile ti yoo si mu ki ese-ile bee maa dan gbinrin.

Aroko Asapejuwe (Ebi Ogbeni Ajayi)


Oruko mi ni Ade Ajayi bee ni mo si je omodekunrin lati ile adulawo, Afirika. Mo n gbe pelu baba mi, iya mi, awon aburo mi lokunrin ati lobinrin. Iyaaya mi ati iya-baba mi n gbe pelu wa bakan naa. Lai fa oro gun, ebi Ogbeni Ajayi ko ju bayii lo.

A n gbe ninu ile ti baba mi ko. Eyi wa ni okan lara awon ileto ti eniyan le ba pade ni Iwo-Oorun Afirika.



Emi ko ga pupo nitori pe mi ko ju omo odun mokanla pere lo. Awon aburo mi lokunrin ati lobinrin keere pelu. Amo awon obi mi ko reere lojo-ori. Ki gan-an lojo-ori won? Emi ko mo. Baba mi ti ju omo odun marundinlogoji sugbon o se e se ki iya mi je omo ogbon odun.

Ni idakeji ewe, awon obi ti o tuko obi mi wale aye ti di arugbo; won yoo ti pe omo aadorin odun. Amo n ko le fogun re gba ori.

Tuesday, November 13, 2018

Orin Etiyeri (Yoruba Musical Satire)


Awon eya Yoruba ti a n pe ni Oyo ni o ni orin etiyeri. Ipa ti orin efe n ko ni Egbado ni orin etiyeri paapaa n ko laarin awon ara Oyo.

Ewi amuludun ni etiyeri n se. Won maa n lo o lati fi parowa awon iwa ibaje ti o n sele lawujo. Nitori pe orin ni, o maa n mu lile ati gbigbe lowo.

Orin etiyeri naa tun wa fun idanilekoo, idanilaraya ati ipanilerin-in tori pe awon oro apara ati awon oro alunfansa maa n tawotase ninu ewi alohun naa.

Ko tan sibe, a tun maa n fi orin eriyeri se iwure.

Awon odomokunrin bi marun-un tabi ju bee ni maa n kora jo korin etiyeri kaakiri adugbo.

Ni aye atijo, onkorin etiyeri maa n wo aso bi egungun sugbon eyi ko ri bee mo lode oni.

Apeere:
Lile:- E maa pe yoo se
Egbe:- A a se
Lile:- Ode roko, ode peran
Egbe:- A a se
Lile:- Eran ki lode pa?
Egbe:- A a se
Lile:- Ode peran okete
Egbe:- A a se
Lile:- Iku a re wa kete
Egbe:- A a se
Lile:- Arun a re wa kete
Egbe:- A a se...

Fun Ekunrere Eko, E Lo Si www.olukoni.blogspot.com

Saturday, November 3, 2018

Gbolohun Onibo VS Awe-gbolohun Afibo


Akiyesi ti fi han gbangba pe awon akekoo maa n gbe alaye oro mejeeji yii funra won. Eyi lo fa a ti a fi pinnu pe ki a to toka si ohun ti o mu gbolohun onibo yato si awe-gbolohun afibo, a oo koko ran a leti oriki gbolohun ati awe-gbolohun.

Ki ni gbolohun? Gholohun ni akojopo oro ti a n lo lati fi gbe ero okan jade ni ibamu pelu ofin isowo-lo-ede. Orisirisi ona ni a le gba pin gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun, ilo, tabi iye oro-ise wo o.


Ki ni awe-gbolohun? Eyi je okan lara koko oro ti a le ri fayo lati inu gbolohun olopo oro-ise. Ninu Gbolohun olopo oro-ise, a maa n ri olori awe-gbohun ati awe-gbolohun afarahe.

Ki ni Gbolohun Onibo? Eyi je okan lara awon gbolohun olopo oro-ise ti a fi gbolohun kan bo inu gbolohun miiran. A maa n lo awon atoka-afikun bi “pe”, “ki”, “lati” lati fi saaju gbolohun ti a fi bo inu gbolohun mii. Apeere: A gbagbo pe iku ni ere ese.

Ki ni Awe-gbolohun afibo? Eyi ni awe-gbolohun ti a fi bo inu gbolohun onibo nipa lilo awon atoka-afikun ti a menu ba ni isaaju. Apeere: …pe iku ni ere ese

Awon ounje Nile Yoruba (Yoruba Indigenous Cuisine)



Okan lara ohun ti o n toka asa ni ounje. Bi a se ni awon ounje ti a le pe ni ti gbogoogbo bee naa ni a ni eyi tii se ti awon Yoruba ponmbele. Kannpa ni ounje fun gbogbo omo adarihurun, eyi lo si fa a ti a fi ni orisirisi owe ajemo ounje nile Yoruba. Owe kan so pe ohun ti eye ba je ni eye n gbe rorun.

Wiwa laaye ati laye eniyan ro mo ounje ti eniyan ba n je. Awon ounje afunni lokun wa, bee naa ni awon ounje amaradan naa wa pelu, eyi lo mu awon Yoruba maa so wi pe ounje lore awo.


Bi o se ti je wi pea won omo Yoruba ko si ni oju kan naa mo, awon kan wa ni Ile-Ife, awon kan wa ni Oye Ekiti, bee sin i awon miiran wa ni Akoko ni ipinle Ondo. Lara ohun adamo fun okookan awon orisirisi ilu nile Yoruba ni ounje wa.

Eyi tumo si wi pe ounje ti o wopo laarin awon eya Yoruba se otooto fun apeere adalu, ebiripo, ifokore, ati bee lo; lo wopo laarin awon Ijebu nigba ti amala-lafun wopo laarin awon Ibadan.

Nipase olaju, orisirisi awon ounje ajeji tabi atohunrinwa lo ti wo orilede Naijiria ti o si ti dapo mo awon ounje ti a mo ni ti eya Yoruba.

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday