Saturday, November 17, 2018

Aro Dida (Yoruba Dye Making)


Awon ohun elo fun aro dida niyi: Omi-aluba, eeru soso-eyin, opolopo omi, ikoko arimole, ikoko kekeeke meji, opa-aro, aso funfun, elu, opon ti o fe ti eniyan le te aso le.

Ise obinrin ni ise yii bee si ni "aredu" je ikini fun awon alaro. Ise alaro ni ki o fi aro bu ewa kun aso nipa rire e sinu aro. Die lara awon ilu ti aro dida ti wopo ni Ibadan, Oyo, Osogbo, Iseyin, Iwo, Ijebu, ati Abeokuta.

Bi aro ko ba mu aso mo, iru aro bee ti sa niyen. Eyi ni won n pe ni okusu aro. Nigba yii, elu (coloring) ti won n lo ko ni wulo mo, won yoo da a nu; eyi ni won n pe ni sakiti.

Okusu aro (aro to ti sa) tun maa n wulo fun kikun ese-ile ti yoo si mu ki ese-ile bee maa dan gbinrin.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday