Thursday, December 20, 2018

Igbeyin Lalayo N Ta (Ori Keta)

Ewu Ina Kii Pa Awodi

Leyin ti Obisesan gba esi idanwo abajade ile-eko Moda, oun ati egbon re (Ejire) wase lo si ilu Ibadan.

O pe, won ko rise sugbon won fi oro lo ore-egbon re. O ni ki won wa pade oun ni afemojumo ojo keji ni eba ona ile-iwosan Adeoyo lati lo si odo eni ti yoo fun won nise.

Ni afemojumo ojo keji, Obisesan ati egbon re ko si owo awon gbomogbomo agbenipa sugbon Olorun ko won yo lowo awon ajinigbe debi pe ede-aiyede be sile laarin ajinigbe ti n je Agbatiogo ati Oro-ejo.

Leyin ti Obisesan ati Ejire (egbon re) bo lowo awon ajinigbe, won ko lati wa ise nilu Ibadan: won pada si Efon lati lo maa wa ise pepeepe ti won yoo maa se.
Kaa Siwaju Sii >>>

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday