Ise Agbe Nise Ile Wa
Obisesan ati egbon re deyin leyin ise alakowe (a-n-so-tai-morun) leyin ti ori ti ko won yo lowo awon agbenipa ni ilu Ibadan.Ni kete ti won pada de aba won ni won ti gbase alagbaro oko koko ni Ikoro ti o wa ni itosi Ijero.
Oruko oluko ti o ni oko koko n je Lakunle, eni ti o ni iyawo meta.
Ile ti su patapata ki Obisesan ati egbon re to de oko baba yii nitori pe won rin ibuso ti o gba won ni wakati meta.
Kaa Siwaju Sii >>>
No comments:
Post a Comment