Sunday, March 4, 2018

Orin Nile Yoruba

rin je akojopo gbolohun ede Yoruba ti afi ohun didun gbe jade. O see patewo si. A le lu ilu sii. A si le jo sii nigba miiran. A tun le sope Orin je ona ti a ngba fi ero in eni han pelu ohun didun lona ti ole gba wu eni ton gboo lori ki o si mu un lokan gidigidi.

Orisirisi Orin ti o wa
1.  Orin ayeye igbeyawo
2.  Orin ayeye ikomojade
3.  Orin ayeye oye jije
4.  Orin Eremode
5.  Orin iremolekun
6.  Orin nibi oku agba / arugbo
7.  Orin imototo
8.  Orin ibowo fagba
9.  Orin iseefe tabi owe
10.Orin amuseya fun apeere
     Ipo ol;a dara o
     Ipo ola,
     Ipo yii wumi lopolpo,
     Mo si maa debe o
     N ko ni k obo na mi lowo
     N ko ko bo na mi laso
     Ma deni Pataki
     Ma deni Olola
     Bori ba joba lola o
mo si maa debe o

IDARAWO
1.     Orin ni o maa n satokun fun ________ (a) ewi (b) ijo (d) erin (e) ija
2.     Irufe orin wo ni ole gba omije loju eni? Orin ti a ko ni ohun _______ (a) gooro (b) isale (d) didun (e) aro
3.     Daruko orisirisi ayeye ti orin kiko ti le waye
4.     Ko orisi orin meta, ki osi so irufe ayeye tabi isele ti a ti le ko okookan

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday