Onka ni Yoruba ma nfi ka nkan lona ti won yoo fi mo iye to oje. Eyi fi han pe ki awon Oyinbo to ko asa mo-on-ko-mo ka de orile – ede Naijiria ni awon Yoruba ti ni imo bi a se nka nnkan.
Onkaye Onkapo
1. Meni Ekinni / kin – in – ni
2. Meji Ekeji / keji
3. Meta Eketa / keta
4. Merin Ekerin / kerin. abbl
Figo Onka Yoruba
42 Eeji le logoji
43 Eetalelogoji
45 Aarundinlaaadota
51 Ookanle laaadota
61 Ookan le logota
63 Eetalelogota
71 Ookan le laaadorin
73 Eeta le laaadorin
81 Eeta le logorin
91 Ookanlelaaadorun
93 Eetalelaaadorun – un
99 Ookan dinlogo run
IDANRAWO
1. So nonba to je iyekan naa pelu Onka Yoruba yii. Aarundinlogun (a) 15 (b)25 (d) 35 (e) 45
2. Kini Onka Yoruba fun 89?(a)OOkandinlaaadorin (b)Ookandinlaaadorun-un (d) Ookandinlogorun – un (e) Ookandinlogorin
3. Ewo ninu nonba wonyi loduro fun aadota? (a) 70 (b) 50 (d) 90 (e) 30
4. Kini Onka Yoruba fun 43? (a) Eetadinlaaadorin (b) Eetadinlogoji (d)Eetalelogoji (e) Eetalelogun
5. Ki ni Onka Yoruba fun 51? (a) Ookanlelogun (b) Ookanlelogota (d)Okanlelogun (e) Ookanlelaaadota
No comments:
Post a Comment