A ti so nipa itan ti o romo bi Oduduwa si de Ile – Ife, ni bayii, a o se ayewo itan bi awon eya Yoruba se wa kaari gbogbo awon ilu ti a mo si ile kaaro-o-jiire
Itan kan so pe Okanbi nikan soso ni Oduduwa bi, Okanbi yii ni a gbo pe o bi omo meje ti eyi akobi re si je obinrin ti obi Olowu. Omo keji ni Alaketu ti o da awon eya Ketu sile, Iketa ni Oba Ibini, Ikerin ni Orangun Ile – Ila, ikarun ni Onisabe ti ile Sabe, Ikefa ni Oluupopo ti I se oba popo, ikeje ni Oranmiyan ti ilu oyo. Nigba ti awon omo wonyi n pin ogun baba won, oba oba Ibini ni o ko awonm (owo eyo), Alaketu ko gbogbo ade, Olowu ko gbogbo aso, Orangun jogun gbogbo iyawo, Onisaba ko gbogbo eran, Olupopo ko gbogbo ileke, Oranmiyan si jogun gbogbo ile.
Igbelewon
Se alaye no soki bi awon omo okanbi se pin ogun babawonA ti so nipa itan ti o romo bi Oduduwa si di Ile – Ife, ni bayii, a o se ayewo itan bi awon eya Yoruba se wa kaari gbogbo awon ilu ti a mo si ile kaaro-o-jiire
Itan kan so pe Okanbi nikan soso ni Oduduwa bi, Okanbi yii ni a gbo pe o bi omo meje ti eyi akobi re si je obinrin ti obi Olowu. Omo keji ni Alaketu ti o da awon eya Ketu sile, Iketa ni Oba Ibini, Ikerin ni Orangun Ile – Ila, ikarun ni Onisabe ti ile Sabe, Ikefa ni Oluupopo ti I se oba popo, ikeje ni Oranmiyan ti ilu oyo. Nigba ti awon omo wonyi n pin ogun baba won, oba oba Ibini ni o ko awonm (owo eyo), Alaketu ko gbogbo ade, Olowu ko gbogbo aso, Orangun jogun gbogbo iyawo, Onisaba ko gbogbo eran, Olupopo ko gbogbo ileke, Oranmiyan si jogun gbogbo ile.
Igbelewon
Se alaye no soki bi awon omo okanbi se pin ogun babawon
No comments:
Post a Comment