Awon Yoruba je iran kan ti o feran ise ati wipe ikini naa tun se Pataki, ko si ohun ti Yoruba kii se ikini le lori bi eniyan nsise, bi eniyan n se ohun ayo, bi eniyan n banuje awon Yoruba yoo ki iru eni bee afi ole nikan ni won maa n ki ni iki egan.
Eje ki a se ayewo awon orisi ikini lenu ise
ISE | IKINI | IDAHUN |
1. Agbe | A-roko-bodun-de o | Ase o |
2. Alagbede | Aroye o | Yo lu irin lati dahun |
3. Ode | Arinpa Ogun o | Ogun yo gbe o |
4.Onidiri | Ojugboro o | Iyemoja a gbe o |
5. Alaro | Arepon | (yoo ni apasa lati fi dahun |
6. Amokoko | Amoye o | Ase o |
7. Atuko | Oko a re to o | Ase o |
8. Babalawo | Aboru-boye o | A-boye-bo-sise |
IGBELEWON
Se alaye orisiikini ti o mo fun awon akeko egbere
No comments:
Post a Comment