Orisirisi itan agboso ni o ro mo itan isedale Yoruba. Amo itan to so pe ile meka ni itan Yoruba ti se gangan ni a o menu ba.
Itan yi fi ye wa wipe Lamurudu baba Oduduwa ni o se awon Yoruba sile ati oun eya kan ti n je Gogobiri ati Kukawa.
Elesin abinibi ni Oduduwa nigba ti baba re si je Elesin Musulumi. Inu bi baba re wipe esin Oduduwa lodi si toun, eyi si da ija sile, ija yii lo mu ki oduduwa ati awon emewa re sa kuro ni ilu meka ti won si tedo si Ile – Ife. Nigba ti won de Ile – Ife, won ba eni ti a npe ni Agbonmiregun (ti oruko re miran sin je Serilu). Agbonmiregun ni o ko won nipa Ifa.
IGBELEWON
So itan isedale Yoruba ti o mo lai wo inu iwe re.
No comments:
Post a Comment