Eka meta ni a le pin alohun si: Ewi, Itan – aroso oloro gere ati ere onitan.
Gbogbo awon igbadun to wa ninu won fun eniyan niyii:
Ilu, Ijo, Orin, Awada, Ifinisefe, Oriki, gbogbo ohun ti a ka sile yii ni igbadun to wa ninu ewi alohun. Awon to gbo ewi yoo ma gbadun ijo ati ilu to tele ewi; won yoo sit un maa janfani oro awada, ifinisefe, ati oriki gbogbo to wa ninu ewi.
Ninu ere onitan, awon omiran yoo maa gbadun ijo, idan ati okiti tita, aso ere ati ogbon isotan to wa ninu ere onitan ti won ba n wo. Awon to saba maa n se ere onitan laye atijo ni awon to mo nipa eegun alare.
Lara igbadun to wa ninu itan aroso oloro – geere alon ni: ipejopo, orin inu alo, ako iwa rere, ogbon isotan, oruko awon eda eda inu itan. Alo pipa je apeere itan – aroso oloro – geere alohun n tori pe won kii ko sile.
Kini iwa omoluabi ti o wa ninu Itan ijapa tiroko
ReplyDelete