Anwoo ti o je eda itan jade iwe mewaa sugbon ko rise. Kaka ki o gba eto ise agbe ti ijoba se fun awon asesejade ti o rise, n se no ohun ati ore n gbe ogun oloro kokeeni lo si Amerika. Awon agbofinro mu anwo won si fi ibon pa oye ore re. wahala be sile laarin karimu, to n se baba Anwo ati iya Anwo ntori pe oku oru ni iya Anwo ati baba Anwo fi irin ajo Amerika naa se. Karimu le iyawo re ati Anwo jade kuro nile leyin ti Anwo pada de ile pelu ore ogbe lori ati lese.
Anwo sa lo si ile ore re Banjo, eni ti o gba eto ise agbe ijoba. Banjo ti di olowo, osi gba Anwo si ise.
Anwo eda Itan.
· Karimu (Baba Anwo)
· Anwo (Olu ede itan)
· Abeo (iya Anwo)
· Banjo (ore oye ati Anwo)
· Oye (ore Anwo)
· Adio (ore Karimu)
· Alake (oun ni ore Abeo)
Asa to suyo ninu itan : Iwure (Karimu wure fun Abeo laaro) Oriki : ( Abeo ki oko re), Orin kiko, Ogede pipe, Ifa dida, Ebo riru.
Koko ti ere dale:-
1. Irin are ti awon odo alainise maa n rin
2. Wahala ti aifenuko to omo maa n fa
3. Owo to dile ni esu n be lowe
4. Ewu to wa ninu gbigbe oogun oloro tokeeni
5. Ise agbe lere
Ihunpo Itan:- (Iran 1) Karimu ati Abeo ji loowuro, Abeo paro fun pe Anwo sun ile sugbon aigboran ni on naa.
(Iran 2) Awon obi ro Anwo pe ki o gba ise agbe ti ijoba la kale sugbon oko.
(Iran 3) Imura Anwo jaa kule nibi ti o ti n wa ise olukoni lodo Saamu.
(Iran 4) Anwo ati oye ko lati se ise agbe.
(Iran 6-7) Ojogbede ati oye n ja nitori Anwoo
(Iran 8-10) O agbofinro te Anwo ati Oye nigba ti won n gbe kokeeni gba Idi – Iroko nibi ti waon asobode wa.
(Iran 11-12) Nibi ipade ebi ti Karimu pe lati fi ejo Abeo sun ni won mu Anwo de pelu ogbe lori ati ese. Won ni ki Abeo gbe omo re pon ntori pe eni bimo oran nipon on. Banjo ti di olowo, o si gba Anwo sile.
No comments:
Post a Comment