Awon ewi alohun naa ni a maa n pe ni ewi abalaye. Ni aye atijo, o un ni awon baba nla wa maa nlo; won kii koo sile ntori wi pe, won ko ni imo mooko – mooka. Orisirisi ona ni a le pin ewi alohun si, lara awon ona naa ni ewi alohun gbogbo – o – gbo, ewi alohun ajero esin, ewi alohun ajemo ayeye (eyi ni a o se agbeyewo re, a o wo awon ilu ti won ti maa n lo won julo ati oro – ise to wa fun awon ewi bee.)
Awon ewi atenudenu to jemo ayeye niwonyii:
Ewi Ilu Oro – ise
i. Rara Oyo Sisun
ii. Ekun iyawo Oyo sisun
iii. Bolojo Egbado kiko
iv.Efe Egbado sise
v. Alamo Ekiti sisa
vi.Olele Ijesa mimu
Vii. Eje / Ariwo Egba Dida
viii.Etiyeri Oyo Kiko
ix. Dadakuada Igbomina Kiko
x. Oku pipe Oyo / Egba Pipe
xi. Apepe Ijebu Kiko
xii. Obitun Ondo Kiko
A maa n ba awon iru ewi alohun wonyi pade nibi aseye lorisirisi bii isile, igbeyawo, ikomojade, oku agba, ati bee lo.
No comments:
Post a Comment