Saturday, March 10, 2018

Ibanisoro Lailo Oro Enu


Ninu asa ti o se Pataki julo ni ede Yoruba ni biba ara eni soro lailo oro enu. Awon Yoruba tile ka omo ti o ba mo oju tun mo ti o gbon ti o si ni aye gidigidi. Yoruba le so igba oro lailo oro enu rara. Omo ti o mo oju ni omo ti a ba soro pelu oju tabi ara ti o si gbo.
Lara awon ona Pataki lati soro lailo oro enu ni:
(1) Ilu: Ni aye atijo, ilu lilu ni awon baba nla wa fi wa n ran se oju ogun. Bi ija ba si gbona awon onilu yoo ma fi ilu ki awon asaaju ogun won maa n fi ilu korin, pa owe, ko ewi.
(2) Agogo: Gbogbo ohun ti a la se pelu ilu – lilu naa ni ale se pelu agogo.
(3) Iwo fifan ati Fere Kakaki: Bi a ba n so nipa fere, eyi le je fere gbigbe, fere kakaki, fere etutu. Enikeni lo le fon fere gbigbe, aiis oba lo ni fere kakaki, awon ode lo ni fere etutu; awon tun le lo fere tiwon nigba ti won ba n sun ijala.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday