Saturday, March 10, 2018

Bi Ede Yoruba Se Di Kiko Sile 2

Awon oyinbo lo mu Yoruba di kiko sile, ki awon oyinbo to de, ko si eto kiko ati kika ede Yoruba. Gbogbo oro abalaye to di kiko sile bayii awon to to maa nsuyo ninu orin, ewi ati itan; ninu opolo ni won maa n ko gbogbo si.
Eyi se se pelu iranlowo awon Yoruba ti won ko leru lo si ilu Amerika ti won da pada si saro leyin owo-eru ti awon oyinbo ijo C.M.S si so di onigbagbo. Ibi itumo Bibeli lati le fi waasu ni kiko ede Yoruba ti bere won yan Alufaa Samuel Ajayi Croether pe ki o seto bi esin igbagbo yoo se wo ile Yoruba. 09-01-1844 ni Alufa Ajayi Crowther koto waasu ni ede Yoruba lara awon oyinbo to tun gbiyanju lati tumo oro miiran si ede Yoruba ni Bowdieh, Clapeston, John CR, Hannah Kilhan ati CA Golloner.
Odun 1844 ni ijo CNS pinnu lati maa lo ede Yoruba fun ise iwasu laarin awon Yoruba.
Henry Venn, Max, Muller, ati awon eniyan miran lo se okunfa bi Bibeli Ede Yoruba se waye.
1852 ni Alufaa Crowther te iwe to pe ni Girama ati fokabulari Yoruba. 

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday