Awon tioto to se Pataki fun sise alaye iro konsonanti niwonyi:
1. Ohun to n sele si tan – an – na
2. Ipo ti afase wa ( riranmu ati airanmu)
3. Ibi isenu pe iro konsonanti
4. Ona isenupe iro konsonanti
(1) Ohun ton sele si tan – an na :- Bi a ba pe iro konsonanti ede Yoruba, isesi tan – an –na le mu ki o wa nipo atunyan tabi aitunyan. Awon iro konsonanti aitunyan ni ( t k p f s s i) nitori eemi to n bo lati edo foro n raye gba tan - an – na koja aisi idiwo. Awon iro konsonanti atunyan ni (b d g gb j l m w y ) nitori eemi to gba inu tan – an – na ko raye koja woorowo.
(2) Ipo ti afase wa (rirammu ati airanmu): iro konsonanti airanmupe ni (b, d, f, g, gb, h, j, k, l, p, r, s, s, t, w, y) nitoripe afase gbe so ke ti eemi si ngba inu enu nahan jade nigba ti a npe awon iro wonyi. Awon iro konsonanti aranmupe ni (m, n) nitoripe afase ko gba soke ti eyi si je ki eemi ti bo lati inu edo foro maa gba eemi ati iho – imu nigba ti a pe awon iro yii.
(3) Ibi isemi pe konsonanti: (a) Afetepe = b, m, (b) Afeyinfetepe = f (d) Aferigipe = t, d, s, l, m,f (e) Afajape = y (e) Afajaferigipe = s, j (f)Afafasepe = k, g (g) Afitan – an – nape = h (gb) Afafasefetepe = p, gb, w.
(4) Ona isenupe iro konsonanti: Eyi amaa salaye ipo afase, iru eemi ti a lo, iwasi eya ara iro. (a) Asenupe = b t d k p gb. Afipe asunsi ati akan mole yoo pade. Afase yoo gbe soke.
(b) Afenupe : f ss h eya ara fun iro pipe yoo sumo ara won ti aaye kekere yoo wa fun emi.
(d) Aseesetan: y w. enu nijan ni eemi maa n gba jade ti a ba pe awon iro wonyi.
(e) Aranmupe : m, n. eemi yoo ma gba iho – imu koja.
(e) Asesi: j. awon afipe re kii tete pinya a o gbo ariwo ti o han daadaa nigba ti a ab pe e.
(f) Afegbe – enu – pe: I. eemi maa n gba egbe enu kan koja nigba ti egbe enu keji ti di pa.
(g) Arehon = r. Ahon maa n re mo erigi oke nigba ti a ba pe iro yii.
No comments:
Post a Comment