Gege bi a ti se mo wipe a le pim faweli Yoruba si ona meji: Aranmupe ati Airanmupe. O se Pataki lati ranti pe gbogbo faweli Yoruba ni atunyan ntori pe tan – an – na ona ofin maa n gbon bi a ba n pe won. Bi a ba fe se alaye faweli Yoruba Yoruba, a o tele awon ilana
a. Riranmu ati Airanmu
b. Giga ahon si aja enu
d. Ibi ti giga ahon nde
e. Irisi ete
e. Isesi ati ipo tan – an – na
a. Riranmu ati airanmu je ise afase. Bi afase ba faye sile fun eemi ti n bo lati odo ikun lati gba imu ati enu, iro ti a o pe yoo je aranmupe ( un, in, en, on, an) bi o ba je enu nikan ni eemi ngba, iro faweli airanmupe ni a o pe bi (I, e, a, u, o, e)
b. Giga enu si aja enu: Bi iwaju ahon ba gbera ahon lo kan aja enu, a o ma ape faweli iwaju (I, e, e, en, in) bi a ba si je pee yin ahon lo gbera gan – an; faweli eyin (o, o, u, on, un) aarin ahon ni faweli aarin (an, a)
d. Ibi ti ahon gade:- faweli ahonpe I & u. faweli ahandiepe (e ati o) faweli ayadiepe e ati o faweli ayanu pe (an, ati o)
e. irisi ete: roboto (o, u, un) tobi perese (a, I, an, in, an)
e. Tan – an –an ona ofun maa n gba nri nigba ti a ba n pe gbogbo awon iro faweli ede Yoruba. Idi niyi ti gbogbo awon fawli ede Yoruba fi je atunyan.
No comments:
Post a Comment