Saturday, March 10, 2018

Bi Ede Yoruba Se Di Kiko Sile

Itan ye wa wi pea won oyinbo ati awon ojise olorun lati America lo koko bere akitiyan kiko ede Yoruba sile. Awon yoeuba ko ni imo mo-on-ko-mo-on-ka gbogbo ohun ti won mo, inu opolo won ni won maa n ko si, gbogbo eti won si maa jeyo ninu itan, orin, ewi, owe, ati bee lo.
   Leyin ti owo – eru ti pari gbogbo awon Yoruba ti won ko leru si ti pada saro ni awon oyinbo ti n ko won pe Eku, E ku ise, e ku ale. Nigba ti awon Yoruba yii wa ona lati maa fie de Yoruba ko oro olorun ati Bibeli ni won yan.
   Alufaa Ajayi Crowther pe ki o seto bi eyi yoo se waye. Niojo kesan-an, osu kiini, odun 1844 ni Ajayi crowther koko fi Yoruba waasu ki o si fi Yoruba so ese Bibeli ti o lo.
   Itan so pea won Oyinbo bi Bowdich, Claperton, John Raban, Hannah Wham; ti koko gbiyanju atiko Yoruba sile. Odun 1844 ni ijo CMS pinnu lati maa fie de Yoruba waasu, eyi si je ki akitiyan lilo ede Yoruba te siwa.
   Henry Venn ti oje akowe-agba fun ijo CMS lato odun 1841 – 1872 gbimo po pelu awon oyinbo bii Max Muhler, Carl Lepcius, Ajayi Crowther,abbl. Lati maa tumo Bibeli si ede Yoruba ni odun 1852, Alufaa Ajayi Crowther te iwe to pe ni “Girama ati Fokabulari ede yoruba”.iwe naa je ipinle Yoruba ode – oni.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday