Saturday, March 10, 2018

Aroko Pipa Laye Atijo


Aroko pipa je ona ti Yoruba maa n gba se ikilo tabi ranse si elomiran laye atijo. Aroko maa nje mo ise, esin tabi egbe ti awon enyan nse. Otito tabi igboran se Pataki ninu aroko pipa. Idi ni yi tio fi je wi pe enikeni tia ba fi aroko ran gbodo je eni ti o feti si ofin ati olotito eniyan.
Awon aroko kan wa ti o maa n wa loju kan, awon aroko wonyi ni a npe ni ate, iru awon aroko bayi wa lati se ikilo ewu.
Laye atijo, orisirisi awon eniyan lo maa n paroko ranse. Die lara won ni:- Ode, Babalawo, awo, ogboni, jagunjagun, agbe, ati bee lo.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday