Lara awon opolopo eya ara ti a nlo fun iro – ede, awon han wa ti a le foju rii, tabi fi dingi wo, awon si wa tii a kole foju ri sugbon ti won n se ise takuntakun ninu pipe iro – ede Yoruba.
Apeere awon ti a le foju ri ni:
a. Enu
b. Imu
d. Ete
e. Eyin
e. Erigi
f. Ahon
g. Aja enu
gb. Afase
h. Olele
i. Ita gogongo
Apeere awon ti a ko le foju ri ni:
a. Edo – foro
b. Komookun
d. tan – an – na ona ofun
e. taa – ofun / ona ofun
e. Inu gogongo
Awon eya ara ti a nlo fun iro – ede pipe
A le pin awon eya ona fun iro – ede pipe si ona meji: 1. Asunsi 2. Akanmole
1. Asunsi: eyi ni awon eya ara fun iro ede to ma n gbera nigba ti a ba n soro. Won le wa soke tabi kiwon lo sile. Isale enu eyi ti a pe ni egbondo ni a ti n ri won. Apeere:- Ete isale, eyin agbon, iwaju ahon, aarin ahon, olele, eyin isale,erigi isale.
2. Akonmole:- Eyi awon eya ara fun iro ede pipe ti won kii kuro ni aye won. Won ma n waa gbari ni oju kan ni. Oke enu ni ati n ri awon wonyi. Apeere:- Ete oke, Erigi oke, Eyin oke, aja enu, afase, ona ofun, iho imu
ISE AMURELE
So alaye ibi ti eemi fun iro ede ti maa jade, ko menu ba liana to eemi tun iro ede
No comments:
Post a Comment