Saturday, March 10, 2018

Ayeye Ati Iwure


Aaro ni Yoruba saba maa n wure fun eniyan. Agba lo si saba maa n se iwure; ope fun ore ni iwure omode fun agba maa nje. Lara awon ohun ti o le fa iwure ni orinayo, igbeyawo, isomo loruko, isinku, oye jije, ile kiko, moto rira.
     Awon aworo orisa lo maa n wure nibi ajodun orisa, awon babalawo ati onisegun lo maa n wure nibi ise won. Awon afobaje lo maa n wure nibi oye jije. Awon agba ati molebi lo maa n wure nibi igbeyawo.
    Awon ohun elo iwure:- Oti oyinbo, oti ibile, oti sekete, obi ati orogbo, ataare, oyin, ireke, iyo, suga, aadun, omi, ati epo.
Ayeye
Iwure
Ajodun
Ododun la ma n rorogbo
Odoodun la a rawusa
Igbeyawo
Eyin iyawo ko ni meeni
Bi ogede eti odo ki ti yagan
Oo ni yagan
Oba
Ade a pe lori
Ejigbaleke a pe lorun

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday