Saturday, July 7, 2018

Igbadun Inu Ere Onitan Alohun



Igbadun Inu Ere Onitan Alohun
Bi tile je pe orisi ayeye ibi ajodun orisa ni a ka kun orisun ere onitan alohun, sibe ti egungun onidan ati ti ere etiyeri lo wopo ju. Die lara awon igbadun ti o wa ninu awon ere onitan alohun niyi:

A. Ijo: Ijo bata ti awon egungun onidan maa n jo wa lara awon ohun ti awon onworan maa n gbadun. Nibi ijo eegun onidan, awon omode lo maa n koko jo leyin naa awon agba yoo bo si oju agbo.

B. Idan ati Okiti tita: Piparada di obo, ekun, ati tita okiti-obo, okiti-agbada, ati bee lo; je ohun ti awon eniyan maa n gbadun.

D. Aso Ere: Awon onworan maa n je igbadun piparo aso ati eku-eegun laikuro ni oju-agbo.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday