Saturday, March 10, 2018

Faweli Ede Yoruba



Ona meji ni ale pin iro ede oruba si:- Iro faweli ati Iro knosonanti. Awon iro faweli ni awon to je pe a maa n pe jade laisi idiwo fun eemi ti n ti nu edo foro bo. Ale pin iro faweli si ona meji. Faweli aranmupe ati faweli airanmupe. Awon iro faweli aranmu pe ni awon faweli ti o nilo eemi edo foro ati eemi  ti o n gba imu. Apere iro faweli aranmupe ni an, in, en, on, un
Awon faweli airanmupe ni awon faweli ti onilo eemi edo foro nikan lati pe won jade. Apere faweli airanmupe;- a, e, e, I, o, o, u.
Awon faweli ede Yoruba le je faweli iwaju, aarin, tabi eyin; osi le je ahamipe, ahamidiepe, ayanupe, tabi ayanudiepe.

No comments:

Post a Comment

Ami Ohun Ati Apeere

Didun ohun se pataki pupo ninu ede Yoruba. Orisi ohun meta ni ede Yoruba ni. Awon ohun naa ni wonyii: (1) Ohun isale (2) Ohun aarin (3) Ohun...

Word of the Day

Quote of the Day

Article of the Day

This Day in History

Today's Birthday

Today's Holiday